adplus-dvertising
Bekeking:Recruitment and School News

WAEC Yoruba Language Questions and Answers 2023/2024 (Objectives and Essay)

WAEC Yoruba Questions and Answers 2023. I will be showing you WAEC Yoruba Language objective and theory questions for free. You will also understand how WAEC Yoruba questions are set and many more examination details.

The West African Examination Council is an examination body that set questions annually from areas students should, after their studies in senior secondary school, be able to write and pass without stress.

WAEC Yoruba answers and questions Objectives and Essay will be provided here in detail and the authenticity of this WAEC 2023 Yoruba solutions to questions have been tested and confirmed to be sure.

WAEC Yoruba Essay And Objective Questions and Answers 2023 (EXPO)

These questions are strictly for practice. The 2023 WAEC Yoruba expo will be posted on this page today, 16th May during the WAEC Yoruba examination. Keep checking and reloading this page for the answers.

WAEC Yoruba 2023 Questions and Answers Loading…

Yoruba OBJ Answers:

1-10: CDBCCDBACC
11-20: DAABACAACB
21-30: DCCAADDACB
31-40: CBDDBAAACD
41-50: BACAADCBCC
51-60: BACABCDCBC


Note: The answers below are for 2022

No 1

Oja je ibi ti karakata ti ma n sele. Awon ti won ni oun jije tabi oun eelo yoo gbe won wa si oja, awon ni a npe ni oloja. Bee ni awon ara ilu ati enikeni ti o ba fera oja yoo wa si inu oja lati wara.

Oruko oja to wa ni ilu mi ni oja Irede, oruko ilu mi ni Awade . O wa lara awon ilu ti a kopo si abe Egbado ti a tun pe ni Yewa. Orisirisi awon oja miiran tun wa ni ilu wa. Awon naa ni oja ita oba, oja sawonjo, oja ilusa ati bee beelo.

Ojo karunkarun ni won maa nna ja Irede. Aarin ilu Awade ni oja naa wa. Oba Ajelanwa ni itan sope o da oja naa sile nibi Ogorun odun seyin. Inu oja yinaa ni idiko awon onimoto wa. Moto to lo si orisi ilu ni o wa nibe. Nibe naa ni awon moto tii won ngbe oja wa lati igberiko, lati wa se oro aje ninu oja nla.

Niso niso ni awon oja naa wa. Biriki ni won sifi ko awon iso towa ninu oja naa. Biso alata sewa ni iso oni gaari wa. Awon iso miiran ni: Elelubo, alagbo,onisu,elepo ati bee beelo. Iso kookan ni o si ni olori iso. Gbogbo oja si ni iya loja ati awon alakoso ati oloye oja.

Oja yii je oja to gbajumo, to si je ilumoka kaakiri ile Yoruba. Enikeni to ba feera gaari, epo tabi egusi ledinwo mo wi pe oja Irede ni o ye ki awon ti rii ra. kosi alajapa kan ti yoo so pe oun o mo Irede. Ti kii ba se ti oja yi ni ko se ni ti yo mo ilu wa. Oja yii lo je ki amo agbegbe naa. Oja yi lo fun ilu yi lokiki. Oun lo je ki ilu naa ni asaaju nile igbimo asofin. Oun naa lo mu ki eto mayederun ijoba fi de odo ti won naa.

Nitori oja yii se pataki fun eto oro aje ipinle Ogun ati ibile ariwa Yewa. Ijoba ti ba won da oda si opolopo ona ti o wo oja naa. Ilu Awade funrare si ngbadun ina ijoba. Omi igbalode wa fun won. Ijoba si fun won ni ile eko alakobere ati ti girama.

Awon asaaju oja Irede naa sin se bebe. Won ni awon owo oja ati iso ti won maa ngba lowo awon oloja. Eleyii ni won fin tun oja yii se. Won kii duro de igba ti ijoba to wa bawon da soro ki won to gbe igbese lori re. Owo yi ni won fi nsanwo awon agbale oja ati awon olode. Ninu re naa, won a yo ti awon oloye oja ati t’ Oba ati awon ijoye won, ninu re naa ni won tin se awon etutu ati awon asa isembaye to ba ye ki won se.

Bi eniyan yoo wa raja ni oja Irede, o gbodo jiwa ni. Afemojumo loja. Nigba yii, eeyan yoo ri oja ra lopo. Owo eni ni oja ni eniyan yoo ti ra ledinwo. Sugbon ti ile ba ti nmo ki eniyan to wara oja, yoo ti ma dowo awon alarobo ti won a ra lati tunta. Awon wonyii yoo ra ledinwo lowo oni nkan won awa gbe owo lee lati tun ta.

Isoro akoko ti mo ri wi pe oja yi ni ni pe, bi won se da oda si awon ona ti o wonu oja yi to, ko si oda ninu oja yii, ti ojo bawa ro ni ki ewa wo arisa oja yi. Erofo yoo ti poju. Awon oko yoo ma wa ri wole. Eleyii kobo ju mu, ki ijoba bawa tun ona inu oja yi se.

Isoro keji ni wi pe, bi eniyan bara oja sile. Ibaaje oja sile meji, awon kan bi egbe omo oni moto yoo de lati wa gba owo lori oja te e ko si le. Iye ti won si maa ngba maa nju tabi ko fere to iye teeyan fira oja yen nigba miran lo. Osi da miloju wi pe kii se gbogbo owo ti won ngba yii lo nde odo ijoba.

yen nigba miran lo. Osi da miloju wi pe kii se gbogbo owo ti won ngba yii lo nde odo ijoba.

2022 WAEC Igbo, Hausa & Yoruba Answers [1st June]
2022 WAEC Igbo, Hausa & Yoruba Answers [1st June]
2022 WAEC Igbo, Hausa & Yoruba Answers [1st June]
2022 WAEC Igbo, Hausa & Yoruba Answers [1st June]

(3a)

Aranmo: ni ki faweli kan ran mo faweli keji. Ninu apalo ni eyi ti maa n sele, iye faweli ati silebu to wa ninu oro mejeeji ti a papo gbodo je iye kan naa pelu eyi ti a seda nipa aranmo.

(3a)

Aranmo: ni ki faweli kan ran mo faweli keji. Ninu apalo ni eyi ti maa n sele, iye faweli ati silebu to wa ninu oro mejeeji ti a papo gbodo je iye kan naa pelu eyi ti a seda nipa aranmo.

Yoruba

—————————————————————

The questions below are not exactly 2023 WAEC Yoruba questions and answers but likely WAEC Yoruba repeated questions and answers.

1a)
Iro akuyun:Awon konsonanti ti agbe jade nigba ti alafo tan-an-na gbon riri
Iro aikunyun:Eyi ni awon konsonanti ti agbe jade nigbati alafo tan-an-na wa ni ipo imi,eemi ri aaye gba inu alafo yii koja woorowo
1b)
Iro akunyun-d,gb,m
Iro aikunyun-p,k,f

2b)
Fa awon awe-gbolohun afarahe ti o wa ninu awon gbolohun isale wonyi yo, ki o si so orisi awe-gbolohun afarahe ti okookan je.

(a)Wale ti a n soro re ti de.

(b)Won ti sun ki a too de.

(d)A o ni jeun bi a ba de.

(e)Omo naa sare nigba ti o ri eegun.

(e)O ya won lenu pe mo di adajo.

See:

How To Pass WAEC Yoruba Examination

The West African Examination Council (WAEC) is a body in charge of the Senior Secondary School Certificate Examination.

The Certificate offered here is a very important credential that awards or certifies the completion of your Secondary School Education.

Have self-confidence

Self-confidence is another factor that affects a candidate’s performance. Promise to do it all by yourself and everything will come out very simple for you.

It is a well-known fact that many students cancel the right answers just to copy the wrong ones because of a lack of self-confidence. Study and pray hard and you are the miracle for the day.

If you have any questions about the 2023 WAEC Yoruba questions and answers, do well to let us know in the comment box.

Last Updated on May 16, 2023 by Admin

Please Share

68 thoughts on “WAEC Yoruba Language Questions and Answers 2023/2024 (Objectives and Essay)”

  1. Please I need question and answer not only for obj and theory

    Reply
  2. Please sir when are you going to release the correct answer

    Reply
  3. Plz sir help us to realease the question and answer for2023/2024

    Reply
  4. What about the Questions and Answers how are we going to see it

    Reply
  5. Pls sir when are you going to release the correct question and answer

    Reply

Leave a Comment

DMCA.com Protection Status